A F’èédú Fan’ná Lyrics by Brymo | Full official mp3 lyrics

Cover Art For A F’èédú Fan’ná Lyrics by Brymo

Brymo Lyrics

The lyrics of “A F’èédú Fan’ná” by Brymo dive deep into themes of longing, emotional fulfillment, and cultural identity. Known for his poetic storytelling, Brymo blends introspection with ancestral influence, reflecting on personal growth and the quest for recognition within society. With its layered meaning, A F’èédú Fan’ná captures the struggle for connection, purpose, and self-discovery, making it one of Brymo’s most thought-provoking works.

Brymo – A F’èédú Fan’ná Lyrics

Verse 1
Iṣe mi ni
Ka ma feedu fọnna
Eruku o wọnu ọbẹ mi
Bi ẹni n logi iṣana
Ọmọ Iya Agba
Awọn Aaba n mẹni mo jẹ
Ọmọde to mọwọ wẹ
Mo n bagba jẹun

Chorus
Bẹ ba ri mi nigboro
Bẹ ba mọ ki mi
Bẹ naka si mi
Ẹ pe mi l’afeedufọnna
Afeedufọnna
Feedu fọnna o
Bẹ ba ri mi nigboro
Bẹ ba ma ki mi
Bẹ naka si mi
Ẹ pe mi l’afeedufọnna

Verse 2
Ọrọ to wa nilẹ
Ọrọ gbogbo wa ni
Alawọ ara a mọra wa
Igbakugba awa ti kọja aala
Ibi o bara rẹ, ah
Jọ ṣe daadaa nibẹ
Ọmọde to mọwọ wẹ
O ma bagba jẹun, ah

Chorus
Bẹ ba ri mi nigboro
Bẹ ba mọ ki mi
Bẹ naka si mi
Ẹ pe mi l’afeedufọnna
Afeedufọnna
Feedu fọnna o
Bẹ ba ri mi nigboro
Bẹ ba ma ki mi
Bẹ naka si mi
Ẹ pe mi l’afeedufọnna

Outro
Afeedufọnna
Feedu fọnna o
Bẹ ba ri mi nigboro
Bẹ ba mọ ki mi
Bẹ naka si mi
Ẹ pe mi l’afeedufọnna

Artist